Qdot – Ayedun Lyrics | Find Out Lyrics
Connect with us

Lyrics

Qdot – Ayedun Lyrics

Qdot Alagbe The Album

Qdot – Alagbe The Album Lyrics

Qdot Ayedun Lyrics

Ayé la b’ówó
Ayé la ma fi sílẹ̀ lọ
Àyànmọ́ pẹ̀lú kádàrá wọn yàtọ̀ sí ra wọn
Òní k’ájá ma gbé nílé, ka yọ kìnìhún sínú igbó
Bó o bá lówó o ti d’awo ilé ayé,
Bó ò lówó lọ́wọ́ o d’ẹrú ayé Ahhh kílódé olówó layé má fún láyè torí olówó layé fẹ́ rí
Ẹlẹ́dàá mi ṣe mí lẹ́ni ayé fẹ́ rí

Ìlú mi tó ń jó, tó ń jó lorí omi ×2
Ẹní lùlù fún ń bẹ ní sàlẹ́, ṣèbí Ọlọ́run ló bá mi ṣé
Ìlú mi tó ń jó, tó ń jó lorí omi
Ẹní lùlù fún ń bẹ ní sàlẹ́, ṣèbí Ọlọ́run ló bá mi ṣé
Ìlú mi tó ń jó, tó ń jó lorí omi

Woooo owó la fí ń ṣe ilé ayé
Ìwà lọ́ ma fí ń ṣe ọ̀run
Bó ṣe lówó tó, lo ma gbádùn òyìnbó tọ́
Ló mú Davido ọmọ bàba olówó paríwo owó ni kókó
Money good oooo
Poverty no sweet oooo my brother

Bó o bá lówó o ti d’awo ilé ayé,
Bó ò lówó lọ́wọ́ o d’ẹrú ayé Ahhh kílódé olówó layé má fún láyè torí olówó layé fẹ́ rí
Ẹlẹ́dàá mi ṣe mí lẹ́ni ayé fẹ́ rí.
Ìlú mi tó ń jó, tó ń jó lorí omi ×2

Ẹní lùlù fún ń bẹ ní sàlẹ́, ṣèbí Ọlọ́run ló bá mi ṣé
Ìlú mi tó ń jó, tó ń jó lorí omi
Ẹní lùlù fún ń bẹ ní sàlẹ́, ṣèbí Ọlọ́run ló bá mi ṣé
Ìlú mi tó ń jó, tó ń jó lorí omi

Ayé dùnnnn
Ayé dùn jẹ jù ìyà lọ
Ayé yìí dùn
Ayé dùn jẹ jù ìyà lọ
Orí ṣe mí olówó ayé
Ayé dùn jẹ jù ìyà lọ
Bí ti Wasiu Àyìndé oooo
Ayé dùn jẹ jù ìyà lọ
Bí ti K1 the Ultimatii
Ayé dùn jẹ jù ìyà lọ
Shout to máyégún gbogbo ilẹ̀ Yorùbá

Written by; Qdot
Released date; 18 November, 2020
Album/EP; Alagbe The Album

Ayedun Lyrics Qdot

Click to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

ADS

ADSS

Like Us On Facebook

AD

Top Lyrics on FOL