Brymo – Méjì Méjì Lyrics

Brymo Méjì Méjì Lyrics, Méjì Méjì Lyrics by Brymo, Brymo Méjì Méjì Lyrics English Translation

Mofiye fo, mo rire
Mowaju mowoke, Ire de
Kijo mole, Motun taka sufe

O dun mo mi oh
O dun mo mi oh
O dun mo mi oh
O dun mo mi oh

Meji Meji ladaye oh (Meji Meji ladaye oh)
Ife re simi O jin gan gan (Meji Meji ladaye oh)

Ore dakun ro koto lo
Motaraka mo subu
Ki n to ko ohun mo n so
Yara gboro, Lora fesi
Esin o gbani, Iwa o Lani
Ohun to wun ni lo n wani
Ore dakun ro koto lo
Motaraka mo subu
Ki n to mo ohun mo n so
Yara gboro, lora fesi
Esin o gbani, Iwa o lani