Brymo – Àkọ́kọ́ Lyrics

Brymo Àkọ́kọ́ Lyrics, Àkọ́kọ́ Lyrics by Brymo, Brymo Àkọ́kọ́ Lyrics English Translation

Emi ni emi leni na
Okunrin meta at’abo to n forin ko
Emi ni emi lomo na
Okunrin merin at’abo won tenu mo
Mo lanu, mo soro
Mo y’ake, mo fo ro
Omo oloforo, Mo j’akara oforo
Emi ni Ah, Emi ni Oh
Emi ma leni to n so nigboro
Emi ni ya, Emi ni yo
Awon mama gan soro ni popo

Won le mi l’akoko
Won le mi l’akoko oh
Won le mi l’akoko oh
Won le mi l’akoko oh

Emi ni, Okunrin na
T’awon majesi sope o’morin gan
Emi ni, emi lomo na
Gbogbo aradugbo lo n tenu mo
Emi baba olowo
Mo sowo, mo jere
Iwa at’opolo lo n lo
Awon ota ti rupo
Emi ni Ah, Emi ni Oh
Emi ma leni to n so nigboro
Emi ni ya, Emi ni yo
Awon omoge redi ni popo

Won le mi l’akoko (Iwo l’akoko)
Won le mi l’akoko oh (Iwo l’akoko oh )
Won le mi l’akoko oh (Iwo l’akoko)
Won le mi l’akoko oh (Iwo l’akoko)
Won le mi l’akoko (Iwo l’akoko)
Won le mi l’akoko oh (Iwo l’akoko oh )
Won le mi l’akoko oh (Iwo l’akoko)
Won le mi l’akoko oh (Iwo l’akoko)