Brymo – Ọkán Mi Ti Fọ́ Wẹ́wẹ́ Lyrics

Brymo Ọkán Mi Ti Fọ́ Wẹ́wẹ́ Lyrics, Ọkán Mi Ti Fọ́ Wẹ́wẹ́ Lyrics by Brymo, Brymo Ọkán Mi Ti Fọ́ Wẹ́wẹ́ Lyrics English Translation

Iyawo kan mi pami lo kiri
Olo’lufoya ni mi oh
Okunrin to le fe meta merin ah
Pe mosa mosa eru demi mole

Okan mi ti fo we we
Okan mi ti pin yele yele
Nigbamiran ife fe mawu lati ewa koro emi mi
Kotun ni wu

Mo mo ose buruku
O file le tipe tipe
Mayo apa mi fun oh
Oun lo ba e ninu je binu mi ndun
Kodara

Okan mi ti fo we we
Okan mi ti pin yele yele
Nigbamiran ife fe mawu lati ewa koro emi mi
Kotun ni wu