Reminisce – Awon Aye Lyrics

Reminisce Awon Aye Lyrics

Awọn aye ẹlẹnu razor
Onisọkusọ
Ẹlẹnu I pass my neighbor
Awọn aye ẹlẹnu razor
Awọn onisọkusọ
Ẹlẹnu I pass my neighbor eh

Money no dey finish, owo no dey tan
Because no be audio, wetin you dey talk
Ẹ kan ma pariwo ni ko sohun tẹ le sọ
Arararara, Ororororo

Nobody shake nobody move
At the same time you snooze you lose
Ẹ ni kuure ẹ ni ṣẹku fun iya Qudus
I promise you ko ni sọ nnkan kan for her to use
For her to use because

Ligaligali awa de o
Ohun to ba wu yin ni ki ẹ ṣe o
Ọmọge jubadi, awa de o
You will never ever find a n**** like me

Awọn aye ẹlẹnu razor
Onisọkusọ
Ẹlẹnu I pass my neighbor (I pass my neighbor o)
Awọn aye ẹlẹnu razor
Awọn onisọkusọ (Onisọkusọ)
Ẹlẹnu I pass my neighbor eh (Ẹlẹnu razor eh)

Owo mi da, 10 meter, 2 meter, 4 meter
5 meter, 6, 20 meter
Ṣa ba mi kowope fun manager

Rọra jẹ ki n fẹnu sọ o
Ṣebi maalu ni wọn ki n fi ẹnu fọn o
Tori pe awọn kan ṣe b’ọn ro po ti tan o
But okay, emi gan-an gan-an ni idan o, ida gan-an gan-an idan o

Ligaligali awa de o
Ohun to ba wu yin ni ki ẹ ṣe o
Ọmọge jubadi, awa de o
You will never ever find a n**** like me

Awọn aye ẹlẹnu razor
Onisọkusọ (Onisọkusọ)
Ẹlẹnu I pass my neighbor (I pass my neighbor o)
Awọn aye ẹlẹnu razor
Awọn onisọkusọ (Onisọkusọ)
Ẹlẹnu I pass my neighbor eh (Ẹlẹnu razor eh)

You know, ko ni tan bẹ
Titi lai lai ati titi lai lai
Ọja D
ENKR
Ẹ ni kuure

    Lyrics Knowledge:

  • Written by: Reminisce
  • Album: ATSG, Vol. 1
  • Released: 2023