Zlatan – Jaboti Lyrics

Zlatan Jaboti Lyrics

(Original)

Ah, say wọ’n fẹ’ mọ idi abájọ jẹ’ju nigga

You say you wan make am, dey pray make I suffer
Enemies go try but back to sender (back to sender)
Man no be God, so me I no dey bother (me I no dey bother)

E geti many reason and it is already written eh
Baba lo ni pé mi ò lè jabọ ah
Say e geti many reason and it is already written eh
Baba lo ni pé kí má lọ ah
Say mi ò lè jabọ jabọ jabọ
Mo jabọ ti e
Ah jabọ jabọ jabọ jabọ
Mo jabọ ti e
Say mi ò lè jabọ ó jabọ ó jabọ ó
Mo jabọ ti e
Mo jabọ jabọ jabọ jabọ jabọ
Mo jabọ ti e

Glory mi sá 240 lórí highwa (highway)
Wahala fún LASTMA to lè (to lè)
Ain’t no change in God’s way
Na why everyday na my birthday
Started from the bottom now we here
Wa ti ma gbọ, Won l’órín lè, Ṣùgbọ́n òun ni ma kọ
Gbedu back in back in every year
Ta ló l’ọmọ, olú k’ọmọ, ìyá lola lo l’ọmọ
Wọn ní brake yẹn tí fail, ní mo ṣe tẹ’na mọ tẹ’na mọ, tẹ’na mọ
Wọn fẹ de’na mọ omọ ó fi rap yẹn pá wọn lọ (ibilẹ)
Kò wọn lọ, j’eju wọn fi effizzy gba ìyàwó wọn
Wọn fẹ ko jabọ, ṣùgbọ́n Olúwa mi ò ju wọn lo

Wọ’n fẹ’ mọ idi abájọ jẹ’ju nigga (eh nigga nigga)
You say you wan make am, dey pray make I suffer (ah suffer suffer)
Enemies go try but back to sender (ah back to sender)
Man no be God, so me I no dey bother (me I no dey bother)

And e geti many reason (ah reason)
And it is already written eh (written)
Baba lo ni pé mi ò lè jabọ eh (mo jabo ti)
Say e geti many reason (reason)
And it is already written ah (it is written)
Baba lo ni pé kí má lọ ah
Say mi ò lè jabọ jabọ jabọ
Mo jabọ ti e
Ah jabọ jabọ jabọ jabọ
Mo jabọ ti e
Say mi ò lè jabọ ó jabọ ó jabọ ó
Mo jabọ ti e
Mo jabọ jabọ jabọ jabọ jabọ
Mo jabọ ti e

Timi jay on the track