FOLA attention Lyrics

You just want to chill, oh
But problem will find you come— for where— the chilling spot

Holiday, holiday mon ami
Kí owó mi dé, hm, màá kokọ lé e wọ̀n dànù
Oh, who dey roll the J?
Tó bá ti wẹ̀, kàn án bá a mu
Èkó ilé, ask my nigga, èmélòó mò ń calcu’

Ẹrù tí mo kack, orí na disturbance
Tọ́kẹ́ ti lé mi Balenciaga
Gettin’ money, gettin’ paid, pẹ̀lú ìkánra
Young money, cash money dey, Barry, rọra
Olè wò kwan kwan mi, ọmọ yìí, rọra

Look am (E be like she do jazz, àbí e ọ̀rí)
Calm down (Aminatu, calm down, ìbàdí rẹ̀)
Ó gaa (Ó ń gbé mi dé bẹ̀)
Àbí o rí dollar? (I go buy latest)

Lifestyle ni ko ni gara
Owo dey, mi o bother
‘Cause her bumbum big, she need pamper
Ko mi lan ni o, when I soco
Mo gbe, oh, won kan ma shakiti bọbọ
Baby, oh, ewa mo combination, motion
Mo ti gba attention mi

Mo ti gba attention mi
That’s my pension ni
Nkan ti mo wọ ni pe
Iwo ni lo ma gba pension mi
Bi n mo fun mi extension mi
Cure pressure yii with one, one Mary Jane
Join me, ka jọ gba lecture yii

Ẹrù tí mo kack, orí na disturbance
Tọ́kẹ́ ti lé mi Balenciaga
Gettin’ money, gettin’ paid, pẹ̀lú ìkánra
Young money, cash money dey, Barry, rọra
Olè wò kwan kwan mi, ọmọ yìí, rọra

Look am (E be like she do jazz, àbí e ọ̀rí)
Calm down (Aminatu, calm down, ìbàdí rẹ̀)
Ó gaa (Ó ń gbé mi dé bẹ̀)
Àbí o rí dollar? (I go buy latest)

Lifestyle ni ko ni gara
Owo dey, mi o bother
‘Cause her bumbum big, she need pamper
Ko mi lan ni o, when I soco
Mo gbe, oh, won kan ma shakiti bọbọ
Baby, oh, ewa mo combination, motion
Mo ti gba attention mi